Jóṣúà 2:7 BMY

7 Àwọn ọkùnrin náà jáde lọ láti lépa àwọn amí náà ní ọ̀nà tí ó lọ sí ìwọdò Jọ́dánì, bí àwọn tí ń lépa wọn sì ti jáde, wọ́n ti ìlẹ̀kùn ẹnu ibodè.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:7 ni o tọ