Jóṣúà 20:3 BMY

3 kí ẹni tí ó bá sèèsì pa ènìyàn tàbí tí ó bá pa ènìyàn láìmọ̀ọ́mọ̀ lè sálọ sí ibẹ̀, fún ààbò lọ́wọ́ olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ ẹni tí ó pa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 20

Wo Jóṣúà 20:3 ni o tọ