Jóṣúà 21:10 BMY

10 (Ilú wọ̀nyí ni a fún àwọn ọmọ Árónì tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú ìdílé Kóhátì tí í ṣe ọmọ Léfì, nítorí tí ìpín àkọ́kọ́ jẹ́ ti wọn).

Ka pipe ipin Jóṣúà 21

Wo Jóṣúà 21:10 ni o tọ