Jóṣúà 21:12 BMY

12 Ṣùgbọ́n àwọn oko àti àwọn abúlé ní agbégbé ìlú náà ni wọ́n ti fi fún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè gẹ́gẹ́ bí ohun ìní rẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 21

Wo Jóṣúà 21:12 ni o tọ