Jóṣúà 21:27 BMY

27 Àwọn ọmọ Gáṣóní idile àwọn ọmọ Lefi ní wọ́n fún lára:“ìdajì ẹ̀yà Mánásè,Gólánì ní Básánì (ìlú ààbò fún apànìyàn) àti Be Ésítarà pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn jẹ́ méjì;

Ka pipe ipin Jóṣúà 21

Wo Jóṣúà 21:27 ni o tọ