Jóṣúà 21:43 BMY

43 Báyìí ni Olúwa fún Ísírẹ́lì ní gbogbo ilẹ̀ tí ó ṣèlérí láti fi àwọn fún baba ńlá wọn. Nígbà tí wọ́n sì gbà á tan wọ́n sì tẹ̀dó síbẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 21

Wo Jóṣúà 21:43 ni o tọ