Jóṣúà 21:8 BMY

8 Báyìí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pín ìlú wọ̀nyí àti ilẹ̀ pápá oko tutù fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ láti ẹnu Móse.

Ka pipe ipin Jóṣúà 21

Wo Jóṣúà 21:8 ni o tọ