Jóṣúà 4:12 BMY

12 Àwọn ọkùnrin Rúbẹ́nì, Gádì àti ìdajì ẹ̀yà Mànásè náà sì rékọjá ní ìhámọ́ra ogun níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, gẹ́gẹ́ bí Móṣè ti pàṣẹ fún wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 4

Wo Jóṣúà 4:12 ni o tọ