Jóṣúà 4:14 BMY

14 Ní ọjọ́ náà ni Olúwa gbé Jóṣúà ga ní ojú gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n sì bẹ̀rù u rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé e wọn, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti bẹ̀rù Móṣè.

Ka pipe ipin Jóṣúà 4

Wo Jóṣúà 4:14 ni o tọ