Jóṣúà 5:12 BMY

12 Mánà náà sì tan ní ọjọ́ kéjì tí wọ́n jẹ oúnjẹ tí ilẹ̀ náà mú jáde; kò sì sí mánà kankan mọ́ fún àwọn ará Ísírẹ́lì, ṣùgbọ́n ní ọdún náà wọ́n jẹ irè oko ilẹ̀ Kénánì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:12 ni o tọ