Jóṣúà 5:15 BMY

15 Olórí ogun Olúwa sì dá a lóhùn pé, “Bọ́ sálúbàtà rẹ kúrò ní ẹṣẹ̀ rẹ, nítorí pé ibi tí ìwọ dúró sí yìí, ilẹ̀ mímọ́ ni.” Jóṣúà sì ṣe bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:15 ni o tọ