Jóṣúà 5:4 BMY

4 Wàyí o, ìdí tí Jóṣúà fi kọ wọ́n nílà nìyìí: Gbogbo àwọn ọkùnrin tí ó ti Éjíbítì jáde wá, gbogbo àwọn ọkùnrin ogun kú ní asálẹ̀ ní ọ̀nà lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:4 ni o tọ