Jóṣúà 6:19 BMY

19 Gbogbo fàdákà àti wúrà àti ohun èlò idẹ àti irin jẹ́ mímọ́ fún Olúwa, wọ́n yóò wá sínú ìsúra Olúwa.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 6

Wo Jóṣúà 6:19 ni o tọ