Jóṣúà 6:4 BMY

4 Jẹ́ kí àwọn àlùfáà méje gbé fèrè ìwo àgbò ní iwájú àpótí ẹ̀rí. Ní ọjọ́ kéje. Ẹ wọ́de ogun yí ìlú náà ká ní ìgbà méje, pẹ̀lú àwọn àlùfáà tí ń fọn fèrè.

Ka pipe ipin Jóṣúà 6

Wo Jóṣúà 6:4 ni o tọ