Jóṣúà 6:7 BMY

7 Ó sì pàṣẹ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ lọ, kí ẹ sì yí ìlú náà ká pẹ̀lú àwọn olùsọ́ tí ó hámọ́ra kọjá ní iwájú àpótí ẹ̀rí Olúwa.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 6

Wo Jóṣúà 6:7 ni o tọ