Jóṣúà 7:6 BMY

6 Jósúà sì fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú àpótí ẹ̀rí Olúwa títí di àṣálẹ́. Àwọn àgbà Ísírẹ́lì sì ṣe bákan náà, wọ́n ku eruku sí orí i wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:6 ni o tọ