Jóṣúà 7:9 BMY

9 Àwọn Kénánì àti àwọn ènìyàn ìlú tí ó kù náà yóò gbọ́ èyí, wọn yóò sì yí wa ká, wọn yóò sì ké orúkọ wa kúrò ní ayé. Kí ni ìwọ ó ha ṣe fún orúkọ ńlá à rẹ?”

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:9 ni o tọ