Jóṣúà 8:17 BMY

17 Kò sì ku ọkùnrin kan ní Áì tàbi Bétélì tí kò tẹ̀lé Ísírẹ́lì. Wọ́n sì fi ìlẹ̀kùn ibodè náà sílẹ̀ ní ṣíṣí, wọ́n sì ń lépa àwọn ará Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:17 ni o tọ