Jóṣúà 9:1 BMY

1 Nísinsinyìí, nígbà tí gbogbo ọba tó wà ní ìwọ̀-oòrùn Jọ́dánì gbọ́ nípa nǹkan wọ̀nyí, àwọn náà tí ó wà ní orí òkè àti àwọn tí ó wà ní ẹṣẹ̀ òkè, àti gbogbo àwọn tí ó wà ní agbégbé Òkun ńlá títí ó fi dé Lẹ́bánónì (àwọn ọba Hítì Ámórì, Kénánì, Pérísì Hífì àti Jébúsì)

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:1 ni o tọ