Jóṣúà 9:13 BMY

13 Àti ìgò wáìnì wọ̀nyí, tí àwa rọ kún tuntun ni, ṣùgbọ́n ẹ wò ó bí wọ́n ti sán. Asọ àti bàtà wa ni ó sì ti gbó nítorí ìrìnàjò ọ̀nà jínjìn.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:13 ni o tọ