Jóṣúà 9:19 BMY

19 ṣùgbọ́n gbogbo àwọn olórí dáhùn pé, “Àwa ti búra fún wọn ní orúkọ Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, a kò sì lè fọwọ́ kàn wọ́n nísinsinyí.

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:19 ni o tọ