Jóṣúà 9:7 BMY

7 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sọ fún àwọn ará Hífì pé, “Ṣùgbọ́n bóyá tòsí wa ni ẹ ń gbé. Báwo ni a ó ṣe lè se àdéhùn pẹ̀lú yín?”

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:7 ni o tọ