Nehemáyà 1:10 BMY

10 “Àwọn ni ìránṣẹ́ rẹ àti ènìyàn rẹ àwọn tí ìwọ rà padà pẹ̀lú agbára ńlá rẹ àti ọwọ́ agbára ńlá rẹ.

Ka pipe ipin Nehemáyà 1

Wo Nehemáyà 1:10 ni o tọ