Nehemáyà 1:2 BMY

2 Hánánì, ọ̀kan nínú àwọn arákùnrin mi wá láti Júdà pẹ̀lú àwọn ọkùnrin kan, mo sì béèrè lọ́wọ́ wọn nípa àwọn Júù tí ó ṣẹ́kù tí wọn kò kó ní ìgbèkùn, àti nípa Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Nehemáyà 1

Wo Nehemáyà 1:2 ni o tọ