Nehemáyà 10:30 BMY

30 “A ti ṣe ìlérí pé, a kò ní fi àwọn ọmọbìnrin wa fún àwọn tí wọ́n wà ní àyíkáa wa bí ìyàwó, tàbí fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wọn fún àwọn ọmọkùnrin wa.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:30 ni o tọ