Nehemáyà 10:33 BMY

33 Nítorí oúnjẹ tí ó wà lóríi tábìlì; nítorí ọrẹ ohun jíjẹ àti ọrẹ ohun ṣíṣun ìgbà gbogbo; nítorí ọrẹ ọjọ́ ìsimi, ti àyájọ́ oṣù tuntun àti àṣè tí a yàn; nítorí ọrẹ mímọ́; nítorí ọrẹ ẹ̀ṣẹ̀ láti ṣe ètùtù fún Ísírẹ́lì; àti fún gbogbo iṣẹ́ ilé Ọlọ́run wa.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:33 ni o tọ