Nehemáyà 11:24 BMY

24 Petaiayọ̀ ọmọ Meṣeṣabélì, ọ̀kan nínú àwọn Ṣérà ọmọ Júdà ní aṣojú ọba nínú ohun gbogbo tí ó jẹ mọ́ ti àwọn ènìyàn náà.

Ka pipe ipin Nehemáyà 11

Wo Nehemáyà 11:24 ni o tọ