Nehemáyà 11:30 BMY

30 Ṣánóà, Ádúlámù àti àwọn ìletò o wọn, ní Lákísì àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Ásékà àti awọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Bíáṣébà títí dé àfonífojì Hínómì.

Ka pipe ipin Nehemáyà 11

Wo Nehemáyà 11:30 ni o tọ