1 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tí ó bá Ṣérúbábélì ọmọ Ṣéálítíélì àti Jéṣúà padà:Ṣeraiáyà, Jeremáyà, Éṣírà,
2 Ámáríyà, Málúkì, Hátúsì,
3 Ṣekánáyà, Réhúmù, Mérémótì,
4 Ídò, Gínétónì, Ábíjà,
5 Míjámínì, Móádáyà, Bílígà,
6 Ṣémááyà, Jóíáríbù, Jédááyà,
7 Ṣálù, Ámókì, Hílíkíyà, àti Jédáyà.Wọ̀nyí ni olóórí àwọn àlùfáà àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn ní ìgbà ayé e Jéṣúà.