2 Ámáríyà, Málúkì, Hátúsì,
3 Ṣekánáyà, Réhúmù, Mérémótì,
4 Ídò, Gínétónì, Ábíjà,
5 Míjámínì, Móádáyà, Bílígà,
6 Ṣémááyà, Jóíáríbù, Jédááyà,
7 Ṣálù, Ámókì, Hílíkíyà, àti Jédáyà.Wọ̀nyí ni olóórí àwọn àlùfáà àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn ní ìgbà ayé e Jéṣúà.
8 Àwọn ọmọ Léfì ni Jéṣúà, Bínúì, Kádímálì, Ṣérébíà, Júdà àti Mátaníyà ẹ̀ni tí òun pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀, ni àkóso orin ìdúpẹ́.