Nehemáyà 13:23 BMY

23 Ní ọjọ́ wọ̀n ọn nì, mo rí àwọn ọkùnrin Júdà tí wọ́n fẹ́ àwọn obìnrin láti Áṣídódù, Ámónì àti Móábù.

Ka pipe ipin Nehemáyà 13

Wo Nehemáyà 13:23 ni o tọ