Nehemáyà 13:9 BMY

9 Mo pàṣẹ kí wọn ya àwọn iyàrá náà sí mímọ́, mo sì kó àwọn ohun èlò ilé Ọlọ́run padà síbẹ̀ pẹ̀lú ọrẹ ọkà àti tùràrí.

Ka pipe ipin Nehemáyà 13

Wo Nehemáyà 13:9 ni o tọ