Nehemáyà 2:1 BMY

1 Ní oṣù Níṣánì (oṣù kẹrin) ní ogún ọdún ìjọba ọba Aritaṣéṣéṣì, nígbà tí a gbé wáìnì wá fún-un, mo gbé wáìnì náà mo fi fún ọba, Ìbànújẹ́ kò hàn ní ojú mi rí ní iwájúu rẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:1 ni o tọ