Nehemáyà 2:20 BMY

20 Mo dá wọn lóhùn, mo wí fún wọn pé, “Ọlọ́run ọ̀run yóò fún wa ní àṣeyọrí. Àwa ìránṣẹ́ rẹ̀ yóò bẹ̀rẹ̀ láti tún un mọ, ṣùgbọ́n fún un yin, ẹ̀yin kò ní ìpín tàbí ipa tàbí ẹ̀tọ́ ohun kóhun tí ó jẹ mọ́ ìtàn ní Jérúsálẹ́mù.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:20 ni o tọ