Nehemáyà 2:7 BMY

7 Mo sì tún wí fún-un pé, “Tí ó bá wu ọba, kí ó fún mi ní lẹ́tà sí àwọn baálé agbégbé Éúfúrétè nítorí kí wọ́n báà lè jẹ́ kí n la ọ̀dọ̀ wọn kọjá lọ sí Júdà láìléwu

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:7 ni o tọ