Nehemáyà 3:10 BMY

10 Ní ẹ̀gbẹ́ èyí Jédáyà ọmọ Hárúmáfì tún èyí tí ó wà ní ọ̀ọ́kán ilé rẹ̀ mọ, Hátúsì ọmọ Háṣábínéjà sì tún tí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ mọ.

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:10 ni o tọ