Nehemáyà 3:23 BMY

23 Lẹ́yìn wọn ni Bẹ́ńjámínì àti Háṣíbù tún èyí ti iwájú ilé wọn ṣe; lẹ́yìn wọn ni, Ásáríyà ọmọ Máṣéyà ọmọ Ananíyà tún ti ẹ̀gbẹ́ ilé rẹ̀ ṣe.

Ka pipe ipin Nehemáyà 3

Wo Nehemáyà 3:23 ni o tọ