Nehemáyà 4:1 BMY

1 Nígbà tí Ṣáńbálátì gbọ́ pé àwa ń tún odi náà mọ, ó bínú, ó sì bínú púpọ̀. Ó fi àwọn ará Júù ṣe ẹlẹ́yà,

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:1 ni o tọ