Nehemáyà 4:10 BMY

10 Lákòókò yìí, àwọn ènìyàn Júdà wí pé, “Agbára àwọn òṣìṣẹ́ ti dínkù, àlàpà púpọ̀ ni ó wà tó bẹ́ẹ̀ tí àwa kò fi le è mọ odi náà.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:10 ni o tọ