Nehemáyà 4:17 BMY

17 Àwọn ẹni tí ó ń mọ odi. Àwọn tí ń ru àwọn ohun èlò ṣe iṣẹ́ náà pẹ̀lú ọwọ́ kan, wọ́n sì fi ọwọ́ kejì di ohun ìjà mú,

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:17 ni o tọ