Nehemáyà 4:23 BMY

23 Bẹ́ẹ̀ ni èmi àti àwọn arákùnrin mi àti àwọn ènìyàn mi àti àwọn ẹ̀ṣọ́ tí ó wà pẹ̀lúù mi kò bọ́ aṣọ wa, olúkúlùkù wa ní ohun ìjà tirẹ̀, kó dà nígbà tí wọ́n bá ń lọ pọn omi.

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:23 ni o tọ