Nehemáyà 4:3 BMY

3 Tóbíyà ará Ámónì, ẹni tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, wí pé, “Ohun tí wọ́n ń mọ—bí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ lásán bá gùn-ún sókè, yóò fọ́ odi òkúta wọn lulẹ̀!”

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:3 ni o tọ