Nehemáyà 4:5 BMY

5 Má ṣe bo ẹ̀bi wọn tàbí wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn nù kúrò níwájúú rẹ, nítorí wọ́n mú ọ bínú níwájú àwọn ọ̀mọ̀lé.

Ka pipe ipin Nehemáyà 4

Wo Nehemáyà 4:5 ni o tọ