Nehemáyà 7:1 BMY

1 Lẹ́yìn ìgbà tí a tún odi mọ tán tí mo sì rì àwọn ìlẹ̀kùn sí ààyè wọn, a sì yan àwọn aṣọ́bodè, àwọn akọrin àti àwọn Léfì.

Ka pipe ipin Nehemáyà 7

Wo Nehemáyà 7:1 ni o tọ