Nehemáyà 7:64 BMY

64 Àwọn wá àkọsílẹ̀ orúkọ ìran wọn, ṣùgbọ́n wọn kò rí í nibẹ̀, fún ìdí èyí, a yọ wọ́n kúrò nínú àwọn tí ń ṣiṣẹ́ àlùfáà gẹ́gẹ́ bí aláìmọ́;

Ka pipe ipin Nehemáyà 7

Wo Nehemáyà 7:64 ni o tọ