71 Díẹ̀ lára àwọn olóórí ìdílé fún ilé ìṣúra ní ọ̀kẹ́ méjì dírámásì wúrà (àádọ́sàn án kílò) (20,000) àti ẹgbọ̀kànlá mínà fàdákà (2,200) (tọ́ùn kan ààbọ̀).
Ka pipe ipin Nehemáyà 7
Wo Nehemáyà 7:71 ni o tọ