Nehemáyà 9:21 BMY

21 Fún ogójì ọdún ni ìwọ fi bọ́ wọn ní ihà; wọn kò ṣe aláìní ohunkóhun, aṣọ wọn kò gbó bẹ́ẹ̀ ni ẹṣẹ̀ wọn kò wú.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:21 ni o tọ