Nehemáyà 9:23 BMY

23 Ìwọ ti mú àwọn ọmọ wọn pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, ó sì mú wọn wá sí ilẹ̀ tí o ti sọ fún àwọn baba wọn pé kí wọn wọ̀, kí wọn sì jogún un rẹ̀

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:23 ni o tọ