Nehemáyà 9:35 BMY

35 Àní nígbà tí wọ́n wà nínú ìjọba wọn, tí wọ́n ń gbádùn oore ńlá tí ìwọ fi fún wọn, ní ilẹ̀ tí ó tóbi tí ó sì lọ́ràá, wọn kò sìn ọ́ tàbí padà kúrò nínú àwọn ọ̀nà búburúu wọn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:35 ni o tọ