Nehemáyà 9:38 BMY

38 “Nítorí gbogbo èyí, a ń ṣe àdéhùn tí ó fẹṣẹ̀múlẹ̀, a sì kọ ọ́ sínú ìwé, àwọn olórí ọmọ Léfì àwọn àlùfáà wọn wa sì fi èdìdì wọn dìí.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:38 ni o tọ